Yoruba Hymn: Oniṣẹgun nla wa nihin – The great Physician now is near

Yoruba Hymn: Oniṣẹgun nla wa nihin – The great Physician now is near

ONIṢẸGUN NLA WA NIHIN – By William Hunter

 

Oniṣẹgun nla wa nihin

Jesu abanidaro;

Oro Rẹ mu ni lara da

A gbọ ohun ti Jesu!


Refrain:

Iro didun lorin Seraf’,

Orúkọ didun ni ahon.

Orin to dun julọ ni:

Jesu! Jesu! Jesu!

 


A fi gbogbo ẹsẹ rẹ ji Ọ,

A gbọ ohun ti Jesu!

Rin lọ s’ọrun lalafia,

Si ba Jesu de ade.

 


Gbogb’ogo fun Krist’ t’O jinde!

Mo gbagbo nisisiyi;

Mo foruko Olugbala,

Mo fe Orúkọ Jesu.

 


Oruko Re l’eru mi lo,

Ko si oruko miran;

Bokan mi ti n fe lati gbo

Oruko Re ‘yebiye.

 


Arakunrin, ẹ ba mi yin,

Ẹ Yin oruko Jesu!

Arabinrin, gbohun soke

Ẹ yin oruko Jesu!

 


Omode at’agbalagba,

T’o fẹ orukọ Jesu,

Le gba ‘pe ‘fe nisisiyi,

Lati sise fun Jesu

 


Nigba ta ba si de ọrun,

Ti a ba si ri Jesu,

A o ko ‘rin yite ife ka,

Orin oruko Jesu. Amin

 

English Version

 

The great Physician now is near,

The sympathizing Jesus;

He speaks the drooping heart to cheer,

Oh hear the voice of Jesus.


Sweetest note in seraph song,

Sweetest name on mortal tongue;

Sweetest carol ever sung,

Jesus, blessed Jesus.

 


Your many sins are all forgiv’n,

Oh, hear the voice of Jesus;

Go on your way in peace to heav’n,

And wear a crown with Jesus.

 


All glory to the dying Lamb!

I now believe in Jesus;

I love the blessed Savior’s name,

I love the name of Jesus.

 


His name dispels my guilt and fear,

No other name but Jesus;

Oh, how my soul delights to hear,

The charming name of Jesus.

 


Come, brethren, help me sing His praise,

Oh, praise the name of Jesus!

Come, sisters, all your voices raise,

Oh, bless the name of Jesus!

 


The children too, both great and small,

Who love the name of Jesus,

May now accept the gracious call,

To work and live for Jesus.

 


And when to that bright world above,

We rise to see our Jesus,

We’ll sing around the throne of love,

His name, the name of Jesus. Amen.

Leave a Reply