Archive For The “Yoruba Hymns” Category

Yoruba Hymn: Si Ọ Olutunu Ọrun – To thee, O Comforter divine

By |

Yoruba Hymn: Si Ọ Olutunu Ọrun – To thee, O Comforter divine

Si Ọ Olutunu Ọrun   1. Si Ọ Olutunu Ọrun Fún ore at’agbara Rẹ A nkọ, Aleluya.   2. Si Ọ, ìfẹ ẹni t’O wa Ninu Majẹmu Ọlọrun A nkọ, Aleluya.   3. Si Ọ, agbara Ẹni ti O nwẹ ni mọ, t’o nwo ni san A nkọ, Aleluya.   4. Si Ọ, Olukọ at’ọrẹ,…

Read more »

Yoruba Hymn – Enikan mbẹ to fẹràn wa – One there is above all others

By |

Yoruba Hymn – Enikan mbẹ to fẹràn wa – One there is above all others

Enikan mbẹ to fẹràn wa A! O fẹ wa Ìfẹ Rẹ ju ti yekan lọ A! O fẹ wa Ọrẹ aiye nkọ wa sile B’oni dun ọla le koro Ṣugbọn ọrẹ yi ko ntan ni A! O fẹ wa     Iye ni fún wa bí a bá mọ A! O fẹ wa Ro b’a…

Read more »

Yoruba Hymn: Mo’n te siwaju lọna na – I’m Pressing On The Upward Way

By |

Yoruba Hymn: Mo’n te siwaju lọna na – I’m Pressing On The Upward Way

Mo’n te siwaju lọna na
Mo’n goke si lojojumọ
Mo n’gbadura bi mo nti lọ
Oluwa jọ gbe mi soke

Read more »

Yoruba Hymn: Wa, ẹnyin olootọ – O come, all ye faithful

By |

Yoruba Hymn: Wa, ẹnyin olootọ – O come, all ye faithful

1. Wa, ẹnyin olootọ, L’ayọ at’isẹgun, Wa kalọ, wa kalọ sí Betlehem, Wa ka lọ wo o! Ọba àwọn Angẹli Ẹ wa kalọ juba Rẹ, Ẹ wa kalọ juba Rẹ Ẹ wa kalọ juba Kristi Oluwa. 2. Olodumare ni, Imọlẹ Ododo, Ko si korira inu Wundia; Ọlọrun papa ni, Ti abi, t’a ko da Ẹ…

Read more »

Yoruba Hymn: Nigbakan ni Bethelemu – Once in royal David’s city

By |

Yoruba Hymn: Nigbakan ni Bethelemu – Once in royal David’s city

Nigbakan ni Bethelemu Ile kekere kan wà. Nibi’iya kan tẹ’mọ rẹ sí Lori Ibujẹ ẹran; Maria n’iya ọmọ na Jésù Kristi l’ọmọ na. O t’ọrun wa sode aiye On L’Ọlọrun Oluwa O f’ile ẹran ṣe ile Bujẹ ẹran fun ‘busun Lọ dọ awọn òtòṣì Ni Jesu gbe li aiye. Ni gbogbo igba ewe rẹ, O…

Read more »

Yoruba Hymn: Ẹ jẹ ka jumọ f’ọpẹ f’Ọlọrun

By |

Yoruba Hymn: Ẹ jẹ ka jumọ f’ọpẹ f’Ọlọrun

Ẹ jẹ ka jumọ f’ọpẹ f’Ọlọrun Orin iyin at’ọpẹ l’o yẹ wa, Ìyanu n’ifẹ rẹ sí gbogbo wa, Ẹ kọrin ‘yin sọba Olore wa.   Refrain: Halleluya! Ogo ni f’Ọlọrun A f’ijo ilu yin Ọlọrun wa, Alaye ni o yin Ọ b’otiyẹ, Halleluya! Ogo ni f’Ọlọrun.     Kil’a fi san j’awọn t’iku ti pa?…

Read more »

Yoruba Hymn: Ọkan mi yin Ọba Ọrùn – Praise My Soul the King of Heaven

By |

Yoruba Hymn: Ọkan mi yin Ọba Ọrùn – Praise My Soul the King of Heaven

Ọkan mi yin Ọba Ọrùn – Henry F. Lyte , 1834 Ọkan mi yin Ọba ọrùn Mu ọrẹ wa s’ọdọ Rẹ ‘Wọ t’a wosan t’a dariji Ta laba ha yin bi Rẹ Yin Oluwa yin Oluwa Yin Ọba àìnípẹkun. Yin fún anu t’O ti fihan F’awọn Baba ‘nu pọnju Yin l’ọkan na ni titi Ọlọra…

Read more »

Yoruba Hymn: Ẹ Yọ Nínú Olúwa, Ẹ Yọ – Be glad in the Lord, and rejoice

By |

Yoruba Hymn: Ẹ Yọ Nínú Olúwa, Ẹ Yọ – Be glad in the Lord, and rejoice

Ẹ Yọ Nínú Olúwa, Ẹ Yọ – Mary E. Servoss   Ẹ yọ nínú Olúwa, ẹ yọ, Ẹyin t’ọkan rẹ ṣe dede; Ẹyin t’o ti yan Oluwa, Le ‘banujẹ at’aro lọ.     Refrain: Ẹ yọ! Ẹ yọ! Ẹ yọ nínú Oluwa ẹ yọ! Ẹ yọ! Ẹ yọ Ẹ yọ nínú Oluwa ẹ yọ!  …

Read more »

Yoruba Hymn: Emi ‘Ba N’ẹgbẹrun Ahọn – Oh, for a thousand tongues to sing

By |

Yoruba Hymn: Emi ‘Ba N’ẹgbẹrun Ahọn – Oh, for a thousand tongues to sing

Emi ‘Ba N’ẹgbẹrun Ahọn – By Charles Wesley , 1739   Emi ‘ba n’ẹgbẹrun ahọn, Fún ìyìn Olugbala, Ogo Ọlọrun Ọba mi Ìṣẹgun ore Rẹ     Jesu tó sẹru wa d’ayọ T’o mu banujẹ tan Orin ni l’eti ẹlẹsẹ Iye at’ilera     O ṣẹgun agbára ẹsẹ O da ondè silẹ, Ẹjẹ Rẹ le…

Read more »

Yoruba Hymn: Oniṣẹgun nla wa nihin – The great Physician now is near

By |

Yoruba Hymn: Oniṣẹgun nla wa nihin – The great Physician now is near

ONIṢẸGUN NLA WA NIHIN – By William Hunter   Oniṣẹgun nla wa nihin Jesu abanidaro; Oro Rẹ mu ni lara da A gbọ ohun ti Jesu! Refrain: Iro didun lorin Seraf’, Orúkọ didun ni ahon. Orin to dun julọ ni: Jesu! Jesu! Jesu!   A fi gbogbo ẹsẹ rẹ ji Ọ, A gbọ ohun ti…

Read more »