Yoruba Hymn Lyrics and Audio: Igbagbo Mi Duro Lori – My Hope is Built on Nothing Else

Listen to audio of the hymn below

 

 1. Ìgbàgbọ mi duro l’ori,

Ẹjẹ at’ododo Jesu,

Nko jẹ gbẹkẹle ohun kan,

Lẹyìn orukọ nla Jesu.

 

Mo duro le Krist’ Apata,

Ilẹ miran, iyanrin ni.

 

 1. B’ire-ije mi tilẹ̀ gún,

Or’-ọfẹ Rẹ ko yípadà,

B’o ti wù kí iji na le to

Idakọro mi ko ni yẹ.

 

Mo duro le Krist’ Apata,

Ilẹ miran, iyanrin ni.

 

 1. Majẹmu, ati ẹjẹ Rẹ,

L’emi ‘o rọ ma bi ‘kun mi dé;

“Gbati ko s’atileyin mọ

On jẹ ireti nla fún mi

 

Mo duro le Krist’ Apata,

Ilẹ miran, iyanrin ni.

 

 1. ‘Gbati’ipe ‘keyin ba sì dùn,

A! Mbá le wa ninu Jésù;

Ki now ododo Rẹ nikan

Ki nduro níwájú itẹ

 

Mo duro le Krist’ Apata,

Ilẹ miran, iyanrin ni.

 

 ENGLISH

 1. My hope is built on nothing less
  Than Jesus Christ, my righteousness;
  I dare not trust the sweetest frame,
  But wholly lean on Jesus’ name.

On Christ, the solid Rock, I stand;
All other ground is sinking sand,
All other ground is sinking sand.

 1. When darkness veils His lovely face,
  I rest on His unchanging grace;
  In every high and stormy gale,
  My anchor holds within the veil.

 

On Christ, the solid Rock, I stand;
All other ground is sinking sand,
All other ground is sinking sand.

 1. His oath, His covenant, His blood,
  Support me in the whelming flood;
  When all around my soul gives way,
  He then is all my hope and stay.

 

On Christ, the solid Rock, I stand;
All other ground is sinking sand,
All other ground is sinking sand.

 1. When He shall come with trumpet sound,
  Oh, may I then in Him be found;
  In Him, my righteousness, alone,
  Faultless to stand before the throne.

 

On Christ, the solid Rock, I stand;
All other ground is sinking sand,
All other ground is sinking sand.

 

Leave a Reply