Yoruba Hymn Lyrics: Ma Kọ́ja Mi, Olùgbàlà – Pass Me Not, O Gentle Savior

Yoruba Hymn Lyrics: Ma Kọ́ja Mi, Olùgbàlà – Pass Me Not, O Gentle Savior
  1. Ma kọ́ja mi, Olùgbàlà

Gbọ ádùrá mi;

‘Gbat’iwọ ba np’elomiran

Máṣe kọja mi.

 

Jésù, Jesu, gbọ adura mi

‘Gbat’iwọ ba np’ẹlomiran,

Máṣe kọja mi.

 

  1. N’itẹ anu, jẹ k’ẹmi ri

Ìtùnú didun

T’ẹdun tẹdun ni mo wolẹ

Jọ, ran mi lọwọ

 

Jésù, Jesu, gbọ adura mi

‘Gbat’iwọ ba np’ẹlomiran,

Máṣe kọja mi.

 

  1. N’igbẹkẹle itoye Rẹ

L’em’o w’oju Rẹ

Wo, ‘banujẹ ọkan mi san

F’ifẹ Rẹ gba mi

 

Jésù, Jesu, gbọ adura mi

‘Gbat’iwọ ba np’ẹlomiran,

Máṣe kọja mi.

 

 

  1. ‘Wọ orisun itunu mi,

Ju’ye fún mi lọ,

Tani mo ni l’ayé lọrùn

Bikòṣe iwọ?

 

Jésù, Jesu, gbọ adura mi

‘Gbat’iwọ ba np’ẹlomiran,

Máṣe kọja mi.

 

English Version

Pass me not, O gentle Savior,

Hear my humble cry;

While on others Thou art calling,

Do not pass me by.

 

Refrain:

Savior, Savior,

Hear my humble cry,

While on others Thou art calling,

Do not pass me by.

 

Let me at Thy throne of mercy

Find a sweet relief;

Kneeling there in deep contrition,

Help my unbelief.

 

Trusting only in Thy merit,

Would I seek Thy face;

Heal my wounded, broken spirit,

Save me by Thy grace.

 

Thou the spring of all my comfort,

More than life to me,

Whom have I on earth beside Thee,

Whom in Heav’n but Thee.

Leave a Reply