Yoruba Hymn: Si Ọ Olutunu Ọrun – To thee, O Comforter divine

Yoruba Hymn: Si Ọ Olutunu Ọrun – To thee, O Comforter divine

Si Ọ Olutunu Ọrun

 

1. Si Ọ Olutunu Ọrun

Fún ore at’agbara Rẹ

A nkọ, Aleluya.

 

2. Si Ọ, ìfẹ ẹni t’O wa

Ninu Majẹmu Ọlọrun

A nkọ, Aleluya.

 

3. Si Ọ, agbara Ẹni ti

O nwẹ ni mọ, t’o nwo ni san

A nkọ, Aleluya.

 

4. Si Ọ, Olukọ at’ọrẹ,

Amọna wa totọ d’opin,

A nkọ, Aleluya.

 

5. Si Ọ, Ẹnití Kristi ran,

Ade on gbogbo ẹbun Rẹ,

A nkọ, Aleluya.

 

English

 

 1. To thee, O Comforter divine,
  for all thy grace and power benign,
  sing we alleluia!

 


 1. To thee, whose faithful love had place
  in God’s great covenant of grace,
  sing we alleluia!

 


 1. To thee, whose faithful power doth heal,
  enlighten, sanctify, and seal,
  sing we alleluia!

 


 1. To thee, by Jesus Christ sent down,
  of all his gifts the sum and crown,
  sing we alleluia!

 

Author: Frances R. Havergal

Leave a Reply