Yoruba Hymn Lyrics: Àpáta Ayérayé, Ṣe Ibí Isadi Mi – Rock of Ages Cleft For Me

Yoruba Hymn Lyrics: Àpáta Ayérayé, Ṣe Ibí Isadi Mi – Rock of Ages Cleft For Me

 

  1. Àpáta ayérayé,

Ṣe ibí isadi mi;

Jẹ kí omi on ẹjẹ,

T’ọsan lati iha Rẹ

Ṣe ìwòsàn f’ẹsẹ mi,

K’o si sọ mi di mímọ

 

  1. K’ise iṣẹ ọwọ mi

Lo le mu ofin Rẹ ṣe,

B’itara mi ko l’arẹ

T’omije mi nṣàn titi,

Wọn kò tó fún ètùtù

‘Wo nikan lo le gbàla

 

  1. Ko s’ohun ti mo mu wa,

Mo rọ̀ mọ agbelebu;

Mo wa k’od’asọ̀ bo mi,

Mo nwo Ọ fún iranwọ;

Mo wà sib’orisun ní,

Wẹ mí, Olugbala mí.

 

  1. ‘Gbati ẹmi mi ba pin,

T’iku ba p’oju mi de,

Ti mbá lọ s’aiye aimọ

Ki nri Ọ n’itẹ ‘dajọ́;

Àpáta ayérayé

Se ibí isadi mi.

 

English
Rock of Ages, cleft for me,

Let me hide myself in Thee;

Let the water and the blood,

From Thy riven side which flowed,

Be of sin the double cure,

Save me from its guilt and power.

 

Not the labor of my hands

Can fulfill Thy law’s demands;

Could my zeal no respite know,

Could my tears forever flow,

All could never sin erase,

Thou must save, and save by grace.

 

Nothing in my hands I bring,

Simply to Thy cross I cling;

Naked, come to Thee for dress,

Helpless, look to Thee for grace:

Foul, I to the fountain fly,

Wash me, Savior, or I die.

 

 

While I draw this fleeting breath,

When mine eyes shall close in death,

When I soar to worlds unknown,

See Thee on Thy judgment throne,

Rock of Ages, cleft for me,

Let me hide myself in Thee.

Leave a Reply