Yoruba Hymns: O Ti Tọ Jesu F’agbara ‘Wenumo – Are You Washed in the Blood?

Yoruba Hymns: O Ti Tọ Jesu F’agbara ‘Wenumo – Are You Washed in the Blood?

O ti tọ Jesu F’agbara ‘Wẹnumọ
   A wẹ ọ ninu ẹjẹ Ọdaguntan
   Iwọ ha ngbẹkẹle ore-ọfẹ Rẹ?
   A wẹ ọ ninu ẹjẹ Ọdaguntan

A wẹ ọ, ninu ẹjẹ,
Ninu ẹjẹ Ọdaguntan fún ọkàn;
Aṣọ rẹ y’o fúnfún y’o sí mo laulau
A wẹ ọ ninu ẹjẹ Ọdaguntan

2. O mba Olugbala rin lojojumo?
   A wẹ o ninu ẹjẹ Ọdaguntan?
   O simile ẹnití a kan mọ igi
   A wẹ ọ ninu ẹjẹ Ọdaguntan

3. Aṣọ  rẹ funfun lati pad’ Olúwa?
   O mọ lau ninu ẹjẹ Ọdaguntan?
   ọkàn rẹ mura fún ‘le didan lókè?
   Ka wẹ ọ ninu ẹjẹ Ọdaguntan

4. Bọ ẹwù ẹri ẹsẹ sí apakan
   Kò sí wẹ ninu ẹjẹ Ọdaguntan
   Isun kan nsàn fún gbogbo Ọkàn aimọ
  Jọ, lọ wẹ nínú ẹjẹ Ọdagutan.

Listen to the rythm here: https://youtu.be/MjYOw2EfQ08

English version
1. Have you been to Jesus for the cleansing pow’r?
Are you washed in the blood of the Lamb?
Are you fully trusting in His grace this hour?
Are you washed in the blood of the Lamb?

Are you washed in the blood,
In the soul-cleansing blood of the Lamb?
Are your garments spotless? Are they white as snow?
Are you washed in the blood of the Lamb?

 1. Are you walking daily by the Savior’s side?
  Are you washed in the blood of the Lamb?
  Do you rest each moment in the Crucified?
  Are you washed in the blood of the Lamb?

 2. When the Bridegroom cometh will your robes be white!
  Are you washed in the blood of the Lamb?
  Will your soul be ready for His presence bright,
  And be washed in the blood of the Lamb?

4 Lay aside the garments that are stained with sin,
And be washed in the blood of the Lamb;
There’s a fountain flowing for the soul unclean,
O be washed in the blood of the Lab

Leave a Reply